Yoruba

Egbe Osise Fesun Kan Awon Oloselu Fun Kiko Oro Ile Yi

Egbe awon osise NLC, ti fesun kana won oloselu atawon ebi won fesun kiko oro ile yi fun arawon.

Aare egbe NLC, Ogbeni Ayuba Wabba, nibi oro ayeye ogota odun ominira ile yi tokasi pe, orileede Nigeria nikan loku larin awon orileede to n fi epo robi sowo sile okere to ko ti ni ebu ifopo.

Ogbeni Wabba ninu atejade tofisita pelu akori Nigeria ni ogota odun, ayeye isokan, sapejuwe aile pese ina oba oni egberun marun megawatt pelu ohun alumoni re, gege bi eyi toburu jai.

Elizabeth Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *