Yoruba

Akose Mose Pe Fun Ogbon Atinuda Lati Mu Eka Eto Ogbin Gbooro.

Ki eto ogbin lee tubo gbooro sii, ile yi gbodo darade ogbon atinuda lori imo ero.

Oga Agba ajo to wa fun ise iwadi lori eto ogbin nile adulawo, FAR, Omowe Yemi Akinbamijo lo soro yi nigbati o n gbe idanileko olosu metameta ti ile eko giga lori imo ijinle ako, tech u, to wa nilu Ibadan kale.

Omowe Akinbamijo eniti o ni idagbasoke teka eto ogbin o lee waye laisi imo ero, to wa gba ijoba lamonran lati samulo awon odo lati lee lo ogbon atinuda won fun atileyin ile yi.

Nigbati o nsoro Giwa ile eko giga Tech u, Ojogbon Ayobami Salami ni ile eko naa ti nseto lati ko awon akeko loke okun lati ni imo ijinle lori imo ekose owo.

Ojogbon Salami ni ile eko naa ti ri owo iranwo lori ise iwadi to to egberun lona aadota Euro gba lati ran won lowo nidi ise iwadi.

 Kehinde/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *