News Yoruba

Ile Igbimo Asofin Apapo Seleri Idajo Ododo Fun Gbogbo Awon Ti Eto Won Tije Titemole.

Adari ile-igbimo Asofin Apapo ile yi, Omowe Ahmad Lawan sope eto idajo too yee kooro yoo wa feniyoowu to ti farakasa iwa ipaa awon iko SARS to ti je tituka.

Ninu atejade kan, nii Omowe Lawan ti sodi mimo pe, gege bi ara ona lati fopin si iwa, tani yio mumi, ile-igbimo Asofin apapo yoo ri dajupe eniyoowu taje iwa ibaje fifowo lile mu ni, baa simo loori fii mu kata ofin koo lee je eko fawon elomiran.

O salaye pea won Asofin yoo sise po pelu awon alakoso lati ridaju pe ibed marun gbogi, iko olufehonuhan Endsars je didahun sii botito ati botiye.

Omowe Lawan ko sai waa ro awon iko alabo lati fese ofin mule jake-jado ile yii ki ijiya si wa fawon taje iwa ibaje ba simo lori.

Net/Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *