News Yoruba

Gomina Akeredolu Seleri Ebun Gbamabinu Fawon Eeyan Ti Dukia Won Baje Nipinle Naa

Gomina ipinle Ondo Oluwarotimi Akeredolu ti seleri lati seto gba mabinu fawon eeyan ti dukia won je bibaje nipinle naa.

Gomina Akeredolu, so eyi lasiko to nba awon Oniroyin soro nilu Akure, leyin to sabewo sawon ibi towoja awon omo isota dee nilu Akure to fi mo Okitipupa nibiti won tii foo ogba ewon.

Gomina sope, iko kan yoo je gbigbe kale ti yoo risi awon dukia to je bibaje fun eto iranwo too ye.

O sodi mimo pea won towote pelu iwa aito konilo laijiya.

Gomina Akeredolu ko sai war o awon araalu lati maa bojuto dukia ijoba toba wa lakata won.

  ODOFIN/IDOGBE

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *