Oludari Agba fajo to n risi isinrulu nile yi NYSC, Ogagun Shuaibu Ibrahim ti seleri titele liana abo covid-19 bo tito ati botiye ni gbogbo ibudo ifinimole towa lorileede yi.

Oludari foro iroyin titun se agbenuso ajo ohun, arabinrin Adenike Adeyemi soro yii nilu Abuja.

Salaye pe, awon alakoso ajo naa yoo tesiwaju lati maa tele liana to ye gbogbo.

Agbenuso ajo NYSC, ko sai war o ijoba lati dakun-dabo mu agbege tooye baa awon ibudo ifinimole jake jado ile yii, lati lee sise to bise, bagbega se n ba iye awon agunbaniro.

 Net/ Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *