Ijoba apapo sope ohun ti ngbe igbese nidi idasile awon ibudo ipese ohun alumoni inu lekun idibo mefefa orileede yi.

Lasiko to nsoro nibi o se ohun alumoni inu ile orileede fodun 2020, Alokoso fohun alumoni inu ile ati idagbasoke re, ogbeni Olamilekan Adegbite sope awon ibudo ohun yoo waa ni toosi awon ibi iwakusa.

O salaye pe, ileese naa yo baa won egbe awakusa soro lati mo awon ohun ti won ni lo.

Ogbeni Adegbite tokasi pea won awakusa alabode nile yii lo nko ida marundinladorun si adorun ise kusa wiwa.

O fikun pe, awon awakusa yii nilo lati jesiese koriya fun lati pere ise lopo yanturu to fimo oro fun orileede Nigeria.

 Net/Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *