Olórí tẹ́lẹ̀rí lórílẹ̀dè yíì, Ajagunfẹ̀yìntì, ọ̀gágun àgbà Yakubu Gowon ti rọ àwọn tọ́rọkàn, àwọn tó ń sàgbékalẹ̀ òfin, àtàwon onímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ, láti ságbékalẹ̀ àwọn ìlànà kan, èyí tí yóò mu àgbéga bá ìlànà ètò ìrìnà lórílẹ̀dè yíì.

Ọgagun àgbà Gowon tó sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ níbi ètò kan tó wáyé nílu Abuja, koroju sí ìgbésẹ̀ báwọn ọkọ̀ kan tó jẹ́ tìjọba se ti dẹnukọlẹ̀ nípinlẹ̀ Èkó nítorí ìfẹ̀húnúhàn fífòpinsí ikọ̀ aláàbo Sars tó wáyé, olórí tẹ́lẹ̀ náà kò sài fikunpé, orílẹ̀dè yíì gbọdọ̀ gùnlé àwọn ìlànà àtẹ́ẹ̀le kan lẹ́ka ètò ìrìnà ilẹ̀ Nàijírìa, kíwọ́n sì mú àtúntó tó gbọgbọ́n ba.

Ajibikẹ/Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *