Home Posts tagged ètò ìrìnà
Yoruba

Olórí tẹ́lẹ̀rí nílẹ̀ Nàijírìa bèèrè fún mímú àgbéga bá ìlànà ètò ìrìnà

Olórí tẹ́lẹ̀rí lórílẹ̀dè yíì, Ajagunfẹ̀yìntì, ọ̀gágun àgbà Yakubu Gowon ti rọ àwọn tọ́rọkàn, àwọn tó ń sàgbékalẹ̀ òfin, àtàwon onímọ̀ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ, láti ságbékalẹ̀ àwọn ìlànà kan, èyí tí yóò mu àgbéga bá ìlànà ètò ìrìnà lórílẹ̀dè yíì. Ọgagun àgbà Gowon tó sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ níbi ètò kan tó Continue Reading