Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì ti rọ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì, láti dènà ìrìnàjò àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ elétò ìlera sáwọn ilẹ̀ òkèrè nínú àbá kan tọ́mọ ilé asòfin náà, ọ̀gbẹ́ni Ganiyu Johnson ló ti késí ilé isẹ́ tó ń rí sọ́rọ̀ isẹ́, ìgbanisísẹ́ àti bọ́wọ́ isẹ́ se ń yáasí láti se ìpèsè isẹ́, kíwọ́n sì ságbékalẹ̀ àwọn ètò kan èyí tí yóò fa ojú àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ onísègùn òyìnbó ọmọ ilẹ̀ yíì tón gbé láwọn òkè òkun mora láti máà sisẹ́ láwọn ọ̀kanòjọ̀kan ilé-ẹ̀kọ́sẹ́ ìsègùn òyìnbó .

Ó wá mẹ́nuba àwọn kùdìẹkudiẹ kan tó n sokùnfà bíkòse sí ìdàgbàsókè kan dàbí alárà bí àisáwọn ohun amáyédẹrùn, àisí ìpèsè àyíká tórọrùn fáwọn òsìsẹ́.

Ajibike/Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *