Ẹgbẹ́ àwọn olùkọ láwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga fasiti, ASUU, ti fòpin sí ìyansẹ́lódì ó lé lósù mẹ́jọ rẹ̀.


Àarẹ ẹgbẹ́ ASUU, nílẹ̀ yíì, Ọ̀jọ̀gbọ́n Biọdun Ogunyẹmi ló sọ èyí di mímọ̀ fáwọn oníròyìn nílu Abuja.


Ọ̀jọ̀gbọ́n Ogunyẹmi sàlàyé pé, ìgbésẹ̀ náà ló wáyé níbamu pèlú àdéhùn àfẹnukò tẹ́gbẹ́ náà se pẹ̀lú ìjọba àpapọ̀ láti yanjú àwọn ǹkan tó sokùnfà ìyansẹ́lódì ọ̀hún.

Aminat Ajibikẹ/Fọlakẹmi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *