Ayipada ihuwasi eda lawon agbegbe ni won ti tokasi gegebi on to sokunfa mimu oju to awon omode ti won ni penija ara nile Naijira.

Oro yi lo tenu awon alejo lori eto ileese Radio Nigeria apapo ile yi ti won pe lede feesi ni Street Children, lade, lasiko ti won nsoro lori, atileyin ajo UNICEF lori riri daju pe won ko deyesi awon omode toje akanda eda.

Okan lara awon alejo, ti o je asoju ajo UNICEF nile yi,  Ogbeni Peter Hawkins tokasi pe ose Pataki kawon agbegbe igberiko mo daju pea won omode to je akanda eda ni o ye ki won ma toju ni gbogbo eka.

Alejo miran lori eto, tise akowe egbe karimajiji, nilu Abuja Ogbeni Mohammed Dantanin nfe ki won gbe awon oluko lo sawon agbegbe yi kawon omode le je anfani eto igbayegbadun to to si won.

KehindeAfonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *