News Yoruba

Egbe Ton Ja Fun Oro To Kan Awujo Pe Fun Sisi Ilewe Ni Ipele-Ipele

Egbe to nja fun oro to kan awujo n fe ki awon ilewe wole pada ni ipele-ipele, yafo fun wiwole ni sansan, lati le fie to abo to muna doko lele fun didena, itankale arun Covid-19 lelekeji.

Alamojuto iko tan mojuto isejoba awarawa ati idagbasoke, NDO, Ogbeni Tajudeen Alabede lo soro yi lasiko to n baa won iko akoroyin sore, lori ipo ti ile yi wa.

Ogbeni Alabede, eni ti Oludari leka to n mojuto ise iwadi, Ogbeni Jelili Adebiyi soju fun, tokasi pe depo wiwole ni sansan awon akeko, yio dara ti won ba wole ni ipele lati le din bi ero yo tip o si nileewe ku.

Ogbeni Alabede, sakiyesi pe ijoba ko ti gbe eto ati liana lawon ileewe, ko to di wipe won wole pada pelu bi aarun Covid-19 se tun be sile lelekeji.

Fasasi/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *