News Yoruba

Ijoba Ipinle Eko N Gbero Lati Ra Abere Ajesara Arun Covid-19

Gomina ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu sope eto isejoba toun nlewaju ti bere sini gbe igbese pelu awon to npese abere ajesara covid-19 lona ati naa.

O sope, ijoba ti n gbero lati fun awon olugbe ipinle Eko ida-adota  labere ajasara.

Gomina so eyi nibi ipade kan nilu Eko.  O salaye pe awon eka aladani kan ti fi ife won has si isunna rira abere ajesara naa, yato si igbese tijoba apapo.

Ipinle Eko toni olugbe toni ogun million, ti ni akosile arun covid-19, egberun marundinladota.

 Net/idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *