News

Ileese Olopa Ni Ipinle Oyo F’awon Olopa Sowo Silu Ago-Are.

Alakoso fun ileese olopa nipinle Oyo, Ngozi Onadeko, sope ilese naa yoo fawon olopa sowo lopo sawon enu iloro to wani Ago-Are, ati Tede nijoba ibile Atisbo nipinle Oyo.

Alakoso so eyi nibi ipade kan to se pelu awon osise eleto abo min ni agbegbe Ago-Are ati Tede nitori aawon to waye lenu loloyi to lowo awon odo agbegbe naa.

O tun salaye pe kose yii to pari, ipade min to tun waaye lati wojutu si gbomisi omi ooto ohun.

Okan lara awon oba-alaye lagbegbe toro naa ti se, Onitede tilu Tede, Oba Abdurauf Adebimpe enito soro loruko akowe re, Kola Ogunronbi benu ate lu iwa kooto awon odo ohun.

Nigba to un fesi, Gomina ipinle Oyo, onimoero Seyi Makinde, eniti Olubadamoran Pataki re foro abo.  Fatai Owoseni sojufun sope, ijoba koni kaare lati fi keele ofin gbe eni yoowu to be nda rugudu sile.

 Oluremi/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *