Igbìmọ̀ atọpinpin elétò ìdájọ́ se se aráàlu nisekuse àtàwọn ìsẹ̀lẹ̀ miin tó fara pẹ́ tí dába owó tó tó billiọnu mọ́kànlélógún naira fún sisan owó gbà mábinú fáwọn tí ọlọ́pa bá gbẹ̀mí wọn lọ́nà àitọ́ pẹ̀lú àwọn ikọ̀ agbófinró mii. Alága ìgbìmọ̀ náà, adájọ́ fẹ̀yìntì Young Ogola ló fojú ọ̀rọ̀ yí Continue Reading
Igbakeji oga olopa nile yi, ekun kokanla, Ogbeni Olasupo Ajani nfe kawon araalu dehin nidi iwa kikolu awon olopa tabi ilese olopa nigba yoowu ti awoo ba waye. Ooga olopa ohun soro yi lasiko ipade re pelu awon torokan eyi towaye lolu ileese olopa, Ibadan. O salaye pe lati igba awoo ifehonnuhan ENDSARS, ibasepo laarin […]Continue Reading
Alakoso fun ileese olopa nipinle Oyo, Ngozi Onadeko, sope ilese naa yoo fawon olopa sowo lopo sawon enu iloro to wani Ago-Are, ati Tede nijoba ibile Atisbo nipinle Oyo. Alakoso so eyi nibi ipade kan to se pelu awon osise eleto abo min ni agbegbe Ago-Are ati Tede nitori aawon to waye lenu loloyi to […]Continue Reading