News Yoruba

Ijoba Apapo Bere Atunse Gbongan Asa To Wa Nilu Eko

Ijoba apapo ti fa gbongan asa tije yi ti a mo si National Theatre fun igbimo awon to n risi oro ifowopamo lati lee satunse re soodi ibudo idanilaraya tipine Eko.

Igbese yi lo waye leyin titowobo ise adehun ati bibuwolu iwe ise akanse to waye nilu Eko laarin asoju ijoba apapo tiise alakoro foro iroyin ati asa, Alhaji Lai Mohammed ati asoju igbimo awon to n risi oro ifowopamo ti Gomina Banki apapo ile yi, Godwin Emefiele soju fun.

Lara awon to tun wa nibe lati tri alakoso foro awon odo ati Ere idaraya, Sunday Dare Gomina Ipinle Eko, Babajide Sanwo-Olu ati Alaga Igbimo awon adari ile ifowopamo, Herbert Wigwe.

Nigbati o nsoro nibi eto naa, Gomina Banki apapo ile yi Godwin Emefiele so wipe atunse ibudu asa ati ibudo idanilaraya tilu Ekoti won ngbero re ni yio pari laarin osun meedogun ti yio si pese ise fawon egberun lona marindinlogoji eniyan.

 Net/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *