News Yoruba

Aare Buhari Jeje Aabo To Gbopon Fun Gbogbo Omo Ile Yi

Aare Muhammadu Buhari ti seleri lati daabobo gbogbo eya ati esin nile yi.

O war o awon Gomina ati awon Oba Alaye lati dena ikunsinu to lee yorisi faa kaja.

Aare Buhari soro yi ninu atejade ti Oluranlowo Pataki lori oro iroyin ati ipolongo re, Mallam Garba Shehu fi sita.

Aare kilo pe oun o ni faaye gba eya tabi esin Kankan lati da wahala sile.

O soro yi bi ijaeleyameya ati rogbodiyan ti se n be sile lawon apa ibikan nile yi nitori iwa odaran tawon daran-daran kan nhu.

Aare bu enu ate lu iru iwa rogbodiyan yi to wa fid a awon eniyan loju wipe ijoba to nlewaju re yio gbe igbese to to lati dena itankale isu awon iwa odaran wonyi.

Net/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *