News Yoruba

Ile America, Ile Asofin Ile Nigeria Kedun Awon To Ba Isele Ijamba Oko Ofurufu Rin

Ile America ati igbimo ile Asofin to nrisi eto irina oju-ofurufu, ti se idaro awon to farakasa ninu isele baalu awon omo ologun to ja lule ni toosi paapaako ofurufu Nnamidi Azikwe, nilu Abuja.

Ninu oro tiwon gbesi oju op ero ayelujara tweeter Asoju ilese America lorilede Nigeria ba ilese naa, ebi awon to farakaasa ati ile Nigeria lapapo kedun.

Bakana, Alaga tekoto ile foro eto irina ofurufu Sheitu Koko, wa seleri pe iwadi to gbooro yoo bere lati moohun to sokunfa isele naa.

Ko sai war o awoneeyan ile Nigeria lati muu suru, fun abajade iwaadi naa, Asofin ohun waa ni igbimo ile ohun yoo sise po pelu awon torokan lati mo ohun to faa isele naa ni pato.

Ninu atejade to fisita, agbenuso ileese ologun oju ofurufu, Ibikunle Daramola, sope oko ofurufu ohun to gbera lati Minna nipinle Niger, lojakule nilu Abuja leyin toko baalu ohun sose le, o fikub pe oga nilese omo-ogun oju ofurufu, ogagun oladayo amoo ti pase iwadi ojuese ohun to sokufa isele naa.

Net/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *