News Yoruba

Ile Asofin Keji Ti Gbaradi Lati Sayemo Fawon Tiwon Fe Yan Sipo Adari Ileese Omo Ologun

Lola ode yi lo sese kile asofin keji buwolu iyansipo awon olori osise titun tare Muhammadu Buhari daabaa.

Iroyin so pe, igbimo tekoto, ti ile yan lati sewadi awon eeyan ohun yoo jabo iwadi won fun ile lola ode yii.

Ninu oro re fawon oniroyin, Alaga igbimo ile foro abo Ogbeni Babajimi Benson, sope igbimo naa ti setan lati fabo re je ile.

Leyin ti ile sayewo awon ti won foruko won sowo lojoru tokoja, ile-igbimo asofin agba sayewo fawon eeyan ohun lotootoo lojob ose tokoja.

Adari ile, Ogbeni Femi Gbajabiamila, sa gbekale igbimo kan, eyiti ogbeni BabajimiBenson lewaju.

 Net/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *