News Yoruba

Asaju Egbe Oselu APC, Bere Fun Isokan Laarin Awon Eeyan Ile Yi

Asaju egbe oselu All Progressives Congress, APC, Senator Bola-Tinubu, ti so idi to fi se Pataki fawon eeyan ile Nigeria lati se arawon lokan, lati fese aseyori to loorin mule lori leede yi.

Senator Tinubu so eyi lasiko to sabewo si Emir Kano, Aminu Ado-Bayero.

Gomina tele nipinle Eko, ohun sope ile Nigeria gbodo ni farada fun arawon gegebi igbese lati fese isokan mule.

O tokasi pe, ipo torileede Nigeria wa bayi nile isokan ati igbora-eni ye fun idagbasoke orileede yi.

Saaju Emir Kano, Ado-Bayero seleri lati sise too agbega ati isokan ile yi.

Net/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *