News Yoruba

Egbe Awon Dokita To Ngba Imo Kun Imo Lati Di Akosemose Sope Awon Yoo Gunle Iyanselodi Lojobo

Egbe awon Dokita, to ngba imo kun imo, lati di akosemose, sope awon yoo gunle iyanselodi alainigbedeke, lojobo tijoba apapo baa kuna lati dahun si ibere won.

Ninu atejade eyi ti won fisita leyin ipade egbe nee nilu Abuja, Aare egbe ohun, Dokitia Uyilawa Okhauaihesuyi ati akowe agba, Dokita Jerry Isogun fowosi bere fun sisan ajeele owo osu oje ese, fawon osise to fimo owo osu keta kosu yi to pari.

Net/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *