News Yoruba

Ileese Aare Yo Ni Ajosepo Pelu Ile Igbimo Asofin Lori Afikun Aba Ofin

Aare Muhammadu Buhari ti se ipade po pelu Aare ile igbimo asofin Ahmed Lawan ati adari ile, Femi Gbajabiamila lati jiroro po lori afikun aba isuna, kaye to yo sile fun owona lori abere ajesara covid-19 ati rira eroja on elo ileese ologun.

Nigba to n soro leyin ipade atilekun morise, Senator Lawan so fun awon akoroyin pe ile asofin ati igbimo isakoso ile asofin ti fenuko pe o se Pataki ki afikun deba aba isuna, ko le fayegba abere ajesara ati eka eto abo.

Senator Lawan so pe ti awon iko abo, ba ri owonaa toto, yo je ki ise won yaa Kankan, kileyi le moribo kuro ninu eto abo to mehen.

Lori oro covid-19, oni ile yi gbodo ro awon onimo nipa science lagbara ki won le sise po pelu awon akegbe won loke okun, lati ipese abere ajesara naa labele, nitoripe orileede yi ko le tesiwaju lati ma gbokan le rira lati oke okun nikan.

Ninu oro Ogbeni Gbajabiamila o to kasi pe, igbimo Pataki ni ile ti gbe kale ti won yo sise lori fife ese abo mule, ti won yo si fi abo iwadi won sowo fun Aare Buhari.

Net/Afonja.

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *