Adari ile igbimo asofin keji nile yi, Ogbeni Femi Gbajabiamila tipe fun ajosepo to danmoraan laarin awon eka ijoba meteeta  to wanile yi kawon omo ile Nigeria le tumbo janfaani ijoba awarawa,

Ogbeni Gbajabiamila lo soro yi nilu Abuja pelu alaye wi pe, gbogbo awon to ba n reti pe ki eka asofin maa woya ija pelu eka alase ijoba ko mo nnkankan nipa pinpin agbara ijoba.

 Adari ile asofin naa tun tanmole si igbagbo awon eeyan  kan wi pe  eka alase lagbara ju eka asofin lo, pe ko ri bee rara bi ko se pe agbara kan naa ni won ni.

O se afikun e pe pelu ilana eto isejoba ile Nigeria, eka isejoba meteeta lo ni ominira, ti won si nilo ifowowewo lona at le seto isejoba nirorun.

Salaudeen

Gbajabiamila pe fun ajosepo to danmoran laarin awon to wa nipo ase.

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *