Bo seku ojo perete ti ere idaraya ile yii to n lo lowo Nipinle Edo yoo wa si ipari, oludari eto gbogbo fun ajo elere idaraya Ipinle Oyo, Ogbeni Kehinde Ojelowo ti soro idaniloju aseyori.

Ogbeni Ojelowo salaye igbagbo re pe iko elere idaraya ipinle oyo yoo gba ju ami goolu merindinlogun ti won gba laakoko idije nan lodun 2018 lo

Nigba ti n ba akoroyin ere idaraya fun illese wa Olaolu Fawole soro nilu Benin , Ogbeni Ojelowo slaye wipe awon elere idaraya Ipinle Oyo yoo gba ami goolu ninu gbogbo ere idaraya ti won ba ti kopa  bii ese kikan, ayo chess, ayo ori tabili, ayo olopon, eleyi ti yio je afikun si ami goolu mewa ti awon elere idaraya Ipinle Oyo ti gba tele.

Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *