News Yoruba

Awon Eeyan Ilu Arigidi Akoko Ati Agbegbe Re Bu Ola Fun Woli T.B. Joshua

Awon oja ati iso itaja to wa nilu Arigidi Akoko lo wa ni titi pa nipa bi won se n daro okan Pataki lara awon omo ilu naa to doloogbe, Woli Temitope Balogun Joshua.

Ilu Arigidi-Akoko nijoba ibile Ariwa-Iwooorun Akoko, Ipinle, Ondo lo je ilu abinibi Woli T.B. Joshua.

Akoroyin wa jabo pe oro ko yato lawon ilu ati ileto to wa ni gbogbo agbegbe naa lati fibu ola Woli to doloogbe naa.

Aafin Oba Ilu Arigidi ati ile Egbon Oloogbe T.B.Joshua lawon eeyan n ya lo lati bawon kedun.

A rii gbo pe won ti siwe ibanikedun si aafin ati ile egbo oloogbe naa pelu bi awon looko looko ati otokulu ilu kaakiri ipinle Ondo se n dedaro akoni ojise Olorun naa.

Kilani/ Babatunde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *