Yoruba

Àjọ Nema Sàfikún Akitiyan Lórí Ìgbáyégbádùn Àwọn Àtìpó

Ọga àgbà àjọ tó ńrísí ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì nílẹ̀ yí, NEMA, Alhaji Mustapha Abeeb ti sèlérí àfikún isapa lórí ọ̀rọ̀ ìgbáyégbádùn àwọn tó laasigbo ti le kúrò nilẹ lapa ìlà orun àríwá ilẹ̀ yí.

Alhaji Abeeb sèlérí ọrọ yí lásìkò tí wọ́n lọ sàbẹ̀wò sí ibùdó àwọn olufiwo bakaasi tó wà ní Maiduguri tíìse olú ìlú ìpínlẹ̀ Borno.

Ó sàlàyé wípé àbẹ̀wò náà jk láti sàyẹ̀wò ibití àwọn obinti wọn ńpèsè fún wọn dé dúró.

Nígbàtí ó ńfèsì, adarí àjọ, NEMA, lẹ́kùn náà, Lydia Magami sọ wípé àjọ náà ti sètò pínpín àwọn ohun ìdẹrùn láti ile de ilẹ olosoosu ni ibùdó náà àti agbègbè tó gbà wọ́n lálejò.

Oluwayemisi Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *