Home Posts tagged NEMA
Environment

5 Die in building Collapse

The National Emergency Management Agency has confirmed the death of five persons as a three-storey building caved in on Ibadan Street, in the Ebute Metta area of the state late Sunday. No fewer than 23 persons including children were said to have been rescued alive. The occupants were said to be in their various apartments […]Continue Reading
Yoruba

Ìsẹ̀lẹ̀ Ilé Wíwó: Àjọ NEMA Àti LASEMA Kéde Iye Èèyàn Tó Gbẹ́mi Mì

Àjọ tón rísí ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì nílẹ̀ yíì, NEMA, àti tìpínlẹ̀ Èkó LASEMA, ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé, àwọn èèyàn tó ti dolóògbe níbi ìsẹ̀lẹ̀ ilé alágà mọ́kànlélógún tó wà nípinlẹ̀ Èkó, jẹ́ méjìlélógún báyíì. Gẹ́gẹ́ báwọn àjọ méjàjì se fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé, méjì lókú àwọn tíwọn sì rí yọ láfẹ̀mójú òní. Sáàjú nìjọba ìpínlẹ̀ […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ Nema Sàfikún Akitiyan Lórí Ìgbáyégbádùn Àwọn Àtìpó

Ọga àgbà àjọ tó ńrísí ìsẹ̀lẹ̀ pàjáwìrì nílẹ̀ yí, NEMA, Alhaji Mustapha Abeeb ti sèlérí àfikún isapa lórí ọ̀rọ̀ ìgbáyégbádùn àwọn tó laasigbo ti le kúrò nilẹ lapa ìlà orun àríwá ilẹ̀ yí. Alhaji Abeeb sèlérí ọrọ yí lásìkò tí wọ́n lọ sàbẹ̀wò sí ibùdó àwọn olufiwo bakaasi tó wà ní Maiduguri tíìse olú ìlú […]Continue Reading
Lifestyle

People Need More Sensitisation On Proper Fire Handling – NEMA Boss

The National Emergency Management Agency, NEMA, has called for more awareness and consciousness of the existence of fire which could lead to loss of lives and properties. The Director-General of NEMA, Retired Air Vice Marshall Mohammed Mohammed made the at a 1-day stakeholders meeting held in Osogbo on the Fire Sensitisation and Awareness Campaign. Our Correspondent Funmi Continue Reading