Yoruba

Ijoba Ipinle Oyo Sawari Awon Osise Ayederu Mokanlelogoji

Igbimo to n mojuto yiye iwe owo wo ati eto atunto n’ileese ijoba nipinle oyo fun odun 2019/2020, ti da laba ki won yo awon osise ti won pe ni ayederu mokanlelogoji kuro lenu ‘se.

Igbimio naa tun fun awon osise miran ti won le ni aadorun niye, ti iwe akole ise won ko baramu, lanfani, lati momo kowe fi ise sile.

Iko alamojuto yi lo fie sun kana won osise to le ni egbeta niye, ti won si da laba lati yo won kuro, lori ate gbigba owo osu, a mo ti igbimo to n wa fun eto atunto, fese awon osise ayederu mokanlelogoji mule, awon mewa to ti papoda ati awon to fee woo igba ni won ni ko lo feyinti.

Ninu atejade eyi ti Oludamoran pataki si gomina lori oro iroyin, Ogbeni Taiwo Adisa, fi sita so pe abo iwadi ni won ti fi sowo ti won yo si je kawon osise to kan mo pato on ti ijoba fe, ki won se.

Iyabo Adebisi/Alolade Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *