Yoruba

Olori Orile Naijiria Nigbakanri Npe Fun Itesiwaju Ibagbepo Alaafia

Olori orile-ede yi nigbakanri, Ogagun feyinti Abdulsalami Abubakar n pe fun gbigba adua fun alaafia ati itesiwaju ninu isokan orile ede Naijiria.

O soro yi ninu oro ikini to fi ranse sawon Musulumi lori ajoyo odun Eid-el-kabir.

Ogagun feyinti Abubakar, sope wiwa nisokan ile yi ni o se pataki to sin lo asiko naa lati rawo ebe sawon to ni okan ayederu, lati yi okan pada nipa gbigba Alafia laye.

O wa gba ladua pe, kolorun Allah fowo bawon lokan, ki won le ni ayidapa okan, pelu afikun pe orile ede Naijiria koni pe bori gbogbo ipenija to n dojuko.

Ololade Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *