Yoruba

Igbese Bere Lori Iforukosile Fawon Omo Ile Nigeria To N Gbe Nilu New York

Nibamu pelu ase ijoba apapo orileede yii, asoju agba fun ile Nigeria n’ilu New York foro number idanmo omo orileede ti soodi mimo pe, gbogbo eto lo ti to lati gunle fiforuko awon omo orileede yii tongbe nilu new york sile fun number idanmo omo ile yii, NIN.

Ogbeni Lot Egopija lo soro yii di mimo nibi ipade gbongan kan to waye nilu New York fawon omo ile Nigeria ton gbe nibe.

O salaye pe, ilese re to gbase latodo ile ise tonrisoro ile okere lati seto iforukosile fawon eeyan re bee lo ni konope tawon yoo fi pari gbogbo eto pelu ajo to nrisoro number idamo omo orilede yii NIMC.

Ogbeni Egopija so pe saaju lon to seleripe, nigbati oun to bo sori  ipo akoso losu die syin oun yoo maa sepade lemolemo pelu awon omo ile Nigeria ton gbe loke okun, keti won maa ba di sohun ton lo.

Folakemi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *