Yoruba

Onimo eto Ilera Ro Ijoba Lati Seranwo Owo Fawon Eeyan Taisan Jedojedo N Ba Finra

Onimo kan nipa aisan jedojedo nile ekose isegun nla uch to wa nilu ibadan, Dokita Adegboyega ipele lati pese iranwo owo fawon eeyan tonpenija aisan jedojedo nitori bowo tiwon fi n setoju aisan naa se po jojo.

Ilu ibadan ni Dokita Akere ti rawo ebe yii lakoko ton ba ile ise Radio Nigeria soro pelu atokasi pe, ko ye kijoba fowo dengbere mu itoju aisan naa, gege bo se lewu koja bawon eeyan se lero.

Bakanna, ninu oro tie, Igbakeji Oludari tele leka tonrisi Itoju Alaisan Nilewosan nla UCH, Dokita Edith Adejoko gbawon omo orilede yii niyanju lati tutata jade lo se ayewo ara won, gege bi igbese akoko lati wo aisan jedojedo naa.

Folakemi Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *