Yoruba

Ijoba Apapo Sefilole Ilana Ateele, Lati Dena Aisan To Maa N Tara Ounje Je Jade

Ijoba apapo orileede yii ti sefilole eto idanileko kan lori aabo ounje je jade.

Alakoso feto ilera Dokita Osagie Ehanire lo seto ayeye ifilole eto idanileko ohun nilu Abuja, pelu  alaye pe, ose pataki ki gbogbo awon toro abo ounje kan gbongbon nile yii forikori, lati sagbekale awon ilana tiwon yoo tele nibi eto idanileko naa, eyi ti yoo mu ki iyato sawon idanileko tawon agbe ti ngba tele lori ipese ounje.

Dokita Ehanire tikun pe awon ilana atteele naa ti yoo ti wa lakosile sinu awon  kan , ni yoo tun wulo fawon allagbata atawon to n ta ounje lona atiridaju pe, abo peye wa lori awon ounje tawon  yoo maa je, ti yoo situn  se dede pelu tile okere.

Alakoso naa sai fikun pe lodun 2010 awon aisan to maa n tara ounje jade bi mokanla logbon lo sekunfa bawon eeyan tole legbeta eeyan bi egberun lona okoolenirinnwo si jalaisi yika agbaye latara re nigba naa lohun.

Folakemi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *