News Yoruba

Awon Asofin N Bere Fun Kin Wo Seranwo Owo F’awon To Ku Die Kato Fun Lawujo

Igbimo asofin agba to n mojuto eka ile ifowopamo ati awon ileese to n mojuto isuna ti ro awon ijoba ipinle, papa awon to wa lekun iwoorun-ariwa, lati ri daju pe won seto iranwo owo fawon to kudie kato fun lawojo.

Won soro amoran yi, nigbati ida aadorin ninu ogoorun awon odo lekun iwo oorun ariwa ni won ko si nibi ti won ti n baa won akoroyin soro nilu Kaduna.

Alaga igbimo ohun, Senator Uba Sani so pe, awon nkan to n fa ipenija yi, ni aisi eto abo, aisi anfani si eka isuna, be lo sir o awon Gomina ni apa Ariwa ile yi lati gbe liana kale, ti yo ran won lowo ni komon kia.

O wa sapejuwe awon ipenija yi gegebi eyi to n dun koko mo eto ati liana ijoba apapo lati madinku de ba ise on osi lawujo.

Alamu/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *