News Yoruba

Awon Akoroyin Ni Iwo-Oorun-Gusu Bu Enu Ate Lu Ikolu To Waye, Ni Ileese Elero Amihunjinjin Amuludun

Egbe awon oniroyin nile yi, (NUJ)  ni ekun guusu iwoorun ile yi ti nu enu ate lu ikolu to waye sile ise Amuludun FM eka ti Radio Nigeria to wa ni Moniya nilu Ibadan.

Atejade latodo igbakeji aare egbe naa lekun yi, Comrade Cosmas Oni ati akowe lekun yi, Bamigbola Gbolafunte ro awon ajo eleto aabo lati tusu de isale ikoko lori isele naa.

Egbe ohun tun kesi ise Olopa ati awon ajo eleto, aabo yoku lati tete sawari awon to wanidi ikolu ile ise iroyin naa.

Won wa kominu lori idi ti awon janduku fi lee kolu ile ise iroyin.

Egbe NUJ wa gboriyin fun ileese olopa fun bi won ti se tete dide lati kappa isele naa.

Alamu/ Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *