News Yoruba

Onímọ̀ Kan Nípa Ètò Ẹ̀kọ́ Dába Lílọ́wọ́ Àwọn Èèyàn Min-In Tọ́rọkàn Bọnu Ìlànà Àkóso Ilé-Ẹ́kọ́ Gíga Varsity

Onímọ̀ kan, nípa ètò ẹ̀kọ́, ọ̀mọ̀wé Father Francis Chiadi ti ké sáwọn tọ́rọkàn nínú ìlànà ìsàkóso ilé-ẹ̀kọ́ gíga fasity láti tẹpẹlẹmọ́ gígùnlé àjọsepọ̀ fún ìdàgbàsókè ẹ̀ka náà.

Ẹniọwọ Father Chiadi ló bèèrè féyi lákokò tón kópa lórí ètò ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ ilé isẹ́ wa kan lede gẹẹsi ta peni striaght talk níkànì Premier f.m .

Ó sàlàyé pé, ìgbésẹ́ lílọ́wọ́ àwọn èèyàn min-in tọ́rọkàn bọnu ìlànà ìsàkóso ié-ẹ̀kọ́ fasity yóò kópa mọ́nigbàgbé sí ìkójú òsùwọ̀n ìlnàna ilé-ẹ̀kọ́ gíga ọ̀hún.

Ó wá gbàwọn alásẹ àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga fasity níyànjú láti sámúlò àwọn ẹgbẹ́ àwọn akẹ́kọ́ọ̀ jáde lkka náà, níwòyesé ipa takuntakun tíwọ́n ńkó àti bíwọ́n se tàn káàkiri àgbáyé.

Kehinde/Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *