Home Posts tagged Father Francis Chiadi
News Yoruba

Onímọ̀ Kan Nípa Ètò Ẹ̀kọ́ Dába Lílọ́wọ́ Àwọn Èèyàn Min-In Tọ́rọkàn Bọnu Ìlànà Àkóso Ilé-Ẹ́kọ́ Gíga Varsity

Onímọ̀ kan, nípa ètò ẹ̀kọ́, ọ̀mọ̀wé Father Francis Chiadi ti ké sáwọn tọ́rọkàn nínú ìlànà ìsàkóso ilé-ẹ̀kọ́ gíga fasity láti tẹpẹlẹmọ́ gígùnlé àjọsepọ̀ fún ìdàgbàsókè ẹ̀ka náà. Ẹniọwọ Father Chiadi ló bèèrè féyi lákokò tón kópa lórí ètò ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ ilé isẹ́ wa kan lede gẹẹsi ta peni striaght Continue Reading