Oga Olapa n’ipinle Oyo, Arabinrin Ngozi Onadeko ti ko awon olopa lo si ile ise ijona to wa l’agodi n’ilu Ibadan lati pinwo rukerudo to be sile lowuro oni nitori bi won ti ni osise Amotekun se sekupa omokunrin kan.

Akoroyin ile is Radio Nigeria to lo wo bi nkan ti ri jabo pea won olopa lo duro wamu wamu nibiti isele naa ti se lagbegbe Uncle Joe ni Mokola nilu Ibadan lona ati da alaafia pada sagbegbe naa.

Saaju ni awon odo kan tinu nbi ti fehonuhan lori bi osise Amotekun kan ti se pa omokunrin omo doun meedogun.

Awon odo yi lo dana sawon oju popo ni mokola, opopna to lo sile ise ijoba ti won is ndukoko mo awon to nrin opopona naa lowuro oni.

Awon toro soju won ti won o so oruko won ni oloogbe, Peter Okafor to nse idanwo oniwe mewa lowo, to tun je omo ekose nibiti won ti won ti ntewe wa lara awon ti awon osise Amotekun nle amo to subu lule nibiti won ti yin nibon.

Titi di igbati a nko iroyin yi jo, awon odo tinu nbi ohun ni won si ko ra won jo sibiti isele naa ti sele laifi bi awon olopa ti se wa lori iduro se.

Rasheedah Makinde/Oluwayemisi Owonikoko

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *