Yoruba

Adari Eto Iroyin Ileese Oloogun Beere Fun Ajosepo Ileese Radio Nigeria Nidi Eto Ironilagbara Awon Osise Re

Adari eto iroyin nileese Oloogun ile yi, Major General Benjamin Sawyer ti bere fun ajosepo pelu ileese Radio Nigeria nidi eto ironilagbara fawon osise re nipe iroyin gbigbe jade lori aseyori ileese ollogun lona ti aabo to peye yoo fi w anile yi.

O pe ipe yi nilu Abuja lasiko to saaju iko awon osise re lenu abewo solu ileese Radio Nigeria, lati se enle n beun si oludari agba ileese Radio Nigeria, Omowe Mansur Liman.

Ogagun Sawyer gbosuba fun leese Radio Nigeria nipa eto ironilagbara fun ileese Radio to je tileese ologun eyi to wa nilu Abuja, o wa pe fun itesiwaju ati ajosepo naa.

Nigba to n fesi, oludari agba ileese Radio Nigeria, Omowo Mansour Lima seleri igbaradi ileese, Radio Nigeria lati je ki ogagun naa se aseye talakan n sepo pelu pipolongo igbokegbodo ilees, oloogun fun isokan ile yi.

Babatunde Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *