Adari eto iroyin nileese Oloogun ile yi, Major General Benjamin Sawyer ti bere fun ajosepo pelu ileese Radio Nigeria nidi eto ironilagbara fawon osise re nipe iroyin gbigbe jade lori aseyori ileese ollogun lona ti aabo to peye yoo fi w anile yi. O pe ipe yi nilu Abuja lasiko to saaju iko awon Continue Reading