Home Posts tagged Naijiria
Yoruba

Àjọ SON, kìlọ̀ fáwọn iléesẹ́ tó ń pèsè irin tútù lórí àmójútó irin-isẹ́ nítorí àwùjọ

Àjọ tó ń rí sí ìpeniye ǹkan ìlò nílẹ̀ Níajírìa SON, ti sèkìlọ̀ fáwọn iléésẹ́ tó ń pèsè irin pé kí wọ́n mójútó àwọn irin-isẹ́ tí wọ́n ńlò fún ìpèsè irin. Olùdarí àgbà àjọ SON, ọ̀gbẹ́ni Farouk Salim tó sípayá ọ̀rọ̀ yí níbi àpéjọpọ̀ kan tó wáyé nílu Abuja sọ́ọ̀ di mímọ̀ pé àjọ náà […]Continue Reading