Agbarijopo egbe awon osise eleto ilera nile Nigeria, JOHESU ti kesi ijobaa papo lati dahun ibeere awon pelu alaye pe gbedeke ojomeedogun tawon fi sita ni ojoketadinlogun osu yi niko nipe tenubodo mo.

Oro ohun lowa ninu atejade latowo alaga apapo egbe ohun, Ogbeni Biobelemoye Josiah.
Egbe ohun salayepe o se Pataki ki joba tete gbe igbese lojuna ati dekun titi pa awon ile iwosan jake jado ile Nigeria.

Egbe ohun ro ile ise eto ilera ijoba apapo lati tete wojutu si oro to je mo igbayegbadun awon osise eleto ilera gege bo se wa ninu afenuko lasiko ipade ifikunlukun to waye.

Banjo/Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *