Gomina Ipinle Ondo, Ogbeni Oluwarotimi Akeredolu ti sagbekale aba eto isuna oni bilionu lanaigba odin mesan o le die fun odun 2022 niwaju ileigbimo asofin.

Aba eto isuna ohun ti won pakori e ni aba eto isuna fun isodotun etooroaje nigomina gbe kale niwaju awona sofin fun ayewo latowo alamojuto feto isuna, Ogbeni Wale Akinterinwa to soju Gomina.

Gomina salaye pe aba eto isuna odun 2022 lo safihan alekun idamesan ole die yato sitodun 2021

Aba eto isuna ohun ni apapo billionumokadinlogorin o le die ti je yiya soto fawon akanse ise, ti bilionumejilelogorun o le die siwa fun owo naa tigbadegba.

Nigba to n soro, adari ileigbimo asofin ipinle Ondo, Ogbeni Bamidele Oleyelogun gboriyin fun gomina Akeredolu fun awon okan o jokan akanse isejakejado ipinle naa.

Abudu/Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *