Home Posts tagged Ipinle Eko
News

Ìpinle eko gbé ìgbésẹ̀ láti forúkọ milliọnu mẹ́ta àwọn olùgbé sínú ìlànà adójútófo ètò-ìlera

Àjọ tó rísí ètò ìlera nípinll Èkó sọpé, ohun ti ńgbé ìgbésẹ̀ láti sàfikún àwọn olùgbé tóòtóò milliọnu mẹ́ta sínú ìlànà ètò ìlera adójútófo ti ìforúkọsílẹ̀ náà yóò sì wáyé lárin ọdún kan. Alákoso àgbà fájọ ọ̀hún Dókítà Emmanuẹla Zamba, sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé ètò ìlanilọ́yẹ̀ àwọn èèyàn ẹsẹ Continue Reading
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ èkó sèlérí pé isẹ́ àkànse kíkọ́ òpópónà apapa yo parí nínú ọdún yí

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti sọpé gbogbo òpópónà àti afárá èyí tí wọ́n ńkọ́ lọ́wọ́ ládugbò Apapa ni yo jẹ píparí nínú osù kẹwa ọdún tawàyí. Gómìnà Babajide Sanwo-olu ló sọ̀rọ̀ ìdánilójú yi lásìkò tó se àbẹ̀wò láti mọ ibi tísẹ́ dé dúró lágbègbè náà, n’ípinlẹ̀ Èkó. Gómìnà Sanwo-olu, sọpé súnkẹrẹ f’àkẹrẹ ọkọ̀, tón f’ojúmọ́ faye […]Continue Reading