Home Posts tagged Adojutofo
Yoruba

Ilé asòfin kejì fi àjọ elétò ìlera adójútófo NHIS, sara àwọn isẹ́ àkànse elẹ́kùnjẹkùn

Ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé asòfin kejì lórí ètò ìlera ti fọwọ́sí titọwọ àjọ elétò ìlera adójútofo, NHIS, bọmu àwọn isẹ́ àkànse tóníse pẹ̀lú ètò ìlera táwọn asòfin máà ń se lẹ́kùn ìdìbò kóòwá wọn. Alága ìgbìmọ̀ tẹkoto le asòfin kejì náà, ọ̀mọ̀wé Tanko Sanunu ló kéde yíì nílu Abuja lákokò tákòwé àgbà àjọ Continue Reading
News

Ìpinle eko gbé ìgbésẹ̀ láti forúkọ milliọnu mẹ́ta àwọn olùgbé sínú ìlànà adójútófo ètò-ìlera

Àjọ tó rísí ètò ìlera nípinll Èkó sọpé, ohun ti ńgbé ìgbésẹ̀ láti sàfikún àwọn olùgbé tóòtóò milliọnu mẹ́ta sínú ìlànà ètò ìlera adójútófo ti ìforúkọsílẹ̀ náà yóò sì wáyé lárin ọdún kan. Alákoso àgbà fájọ ọ̀hún Dókítà Emmanuẹla Zamba, sọ èyí di mímọ̀ níbi ìpàdé ètò ìlanilọ́yẹ̀ àwọn èèyàn ẹsẹ kùkú àti ìgbésẹ̀ iforukọ […]Continue Reading