Won ti gbawon eeyan to dipo oselu mu niyanju lati maa samulo awon inkan to romo eto isejoba to jiire nipase sise tokatokan.

Eekan kan ninu egbe oselu People’s Democratic Party, PDP, Ogbeni Michael Ale lo siso loju oro yii lakoko to n kopa ori eto ile ise, Radio Nigeria kan lede geesi tapeni Political Space.

O tokasi pe, awon oloselu gbodo oselu sise gege bi pe lati sise sin araalu, lona ati nawoja eredi ijoba awarawa dodo araalu.

Ogbeni Ale, to tun je onimo kan nipa awon ise idagbasoke karoju si igbese bawon eeyan se n gbe awon kan igbalode laisiketa lorilede yi, ko sijoba lati wa n kan se si nipa sisagbekale awon liana atele fawon to n gbe

Fadahunsi/Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *