Home Posts tagged Professor Mojisola Adeyeye
Yoruba

Àjọ NAFDAC Ti Àwọn Ilésẹ́ Tó Ńpèsè Omi Inú Ọ̀rá Mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n Pa

Àjọ tó rísí ìpeniye ónjẹ àtòògùn nílẹ̀ yíì, NAFDAC, ti gbé àwọn ilésẹ́ tó ńpèsè omi mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n pa nótorí àigbéwọ̀n tóò àwọn ilésẹ́ náà. Olùdarí àgbà NAFDAC, Ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisọla Adeyẹye ẹnitó sọ èyí nípasẹ̀ asojú àti olùdarí ẹ̀ka ọ̀rọ̀ àwùjọ, Ọ̀mọ̀wé Jimọh Abubakar sàlàyé pé, ìgbésẹ́ náà níse pẹ̀lú àisí ìmọ̀tóòtóò tópéye àwọn ilésẹ́ ọ̀hún. […]Continue Reading