Ilé ẹ̀kọ́ àwọn ọmọ ológun ilẹ̀ yíì, NDA, ti sọ pé irọ́ tó jìnnà sóòtọ ni ọ̀rọ̀ kan tón tan káàkiri pé, òun kò fòfin mú òsìsẹ́ òun kan Torsabo Solomon, lórí bíwọ́n se ló lọ́wọ́ nínú ìkọlù tó wáyé nile ẹ̀kọ́ ọhun.

Tó sì ní lọ́wọ́lọ́wọ́ báyíì onitohun wá lahamọ àwọn báyíì.

Àtẹ̀jáde kan tagbenusọ ilé ẹ̀kọ́ NDA, ọ̀gágun Bashir Jajira fisita sọpé mímú táwọn mú ọ̀gbẹ́ni Solomọn kòníse pẹ̀lú ìkọlù tó wáyé nílé ẹ̀kọ́ ọ̀hún.

Níbàyíná, awuyewuye tin wáyé lórí bíwọ́n se mú ọkùnrin náà wípé oni ǹkanse pẹ̀lú ìkọlù ilé-ẹ̀kọ́ ọ̀hún níbití wọn ti sekúpa àwọn òsìsẹ́ ọlọ́pa méjì tíwọ́n sí jí ọ̀kan gbélọ.

Fọlakẹmi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *