Ile igbimo asofin apapo keji ti nbenu ate lu igbese ile geese bose fifofinde eto irin ago awon eeyan ile yii sorileede ohun.

Awon asofin yi ninu ero otooto won bere fun igbese dide ofin ohun.

Nibi ijoko ile, awon asofin ohun nii, orileede Nigeria atawon ile American yooku lawon ile okeere ndun koko mo, nitori biwon se n kuna lati magbega ba eto oro- aje won.

Adari omo-egbe tokereju nile asofin, Ogbeni Ndudi Elumelu, gbe aba kan kale tope ni Pataki didasi fifofinde fifun awon eeyan ile yi ni iwe irinna latodo ijoba ile geesi, eyiti awon asofin tewogba leyin opolopo ariyanjiyan.

Nigba ti won ntewogba aba ohun, ile wa kanpa fun igbimo re foro ilera, ati tile okeere lati sise po, pelu awon ilese ilera ati tile okeere tofimo igbimo amuseya ijoba apapo farun covid – 19, lori ona abayo gbogi lati wojutu soro naa.

NET/Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *