Ile igbimo asofin ipinle Oyo ti roe ka alase nipinle Oyo lori titejade ohun ifilede gbogbo aba tile igbimo ohun ti so dofin. Ipe naa lo tele oro lori Pataki tetejade to fi mo fifelede awon ofin ohun ti asofin to n soju ekun idibo Ariwa Ogbomosho, Arabinrin Olawumi Oladeji gbe siwaju ile. Nigba Continue Reading
Ile igbimo asofin apapo keji ti nbenu ate lu igbese ile geese bose fifofinde eto irin ago awon eeyan ile yii sorileede ohun. Awon asofin yi ninu ero otooto won bere fun igbese dide ofin ohun. Nibi ijoko ile, awon asofin ohun nii, orileede Nigeria atawon ile American yooku lawon ile okeere ndun koko mo, […]Continue Reading
Ile igbimo asofin ti ro ijoba apapo lati da igbese eto ikaniyan to ye ko waye ninu odun 2021, tawayi duro, eyi ti ajo to n kaniyan nile NPC yi ngbero lati dawole duro naa nitori eto ebo to mehe. Asofin kan, Ogbeni Shehu Beji, lo daba yi, lasiko ijoko ile, to si koroju si, […]Continue Reading
Lasiko ijoko ile, lati mu ki agbega de ba ilese ohun, ati aba ofin lori idasile ileeko ti won yo ti maa ko nipa ile olopa, Ogbeni Yusuf Gagdi tenumo ipinnu ile ise olopa atawon eka to se koko. Gegebi asofin naa tiwi, gbigbe liana kale ti yio risi asiko ti IGP yoo lo ninu ofiisi […]Continue Reading