News Yoruba

Àjọ Ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ Rọ Àwọn Ọmọ Ilẹ̀yí Láti Wà Ní Kíkẹ́ Bí Ìbọn Lórí Gbọnmọgbọnmọ Ìwà Ọ̀daràn

Àjọ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́ DSS, ti sọpé ó seese kí ìwà ìjínigbé, ìsekúpani àti ìdigunjalè pọ̀si lásìkò pọ̀pọ̀sìnsìn ọdún tawàyí.

Agbẹnusọ àjọ ọ̀hún, ọ̀mọ̀wé Peter Afunanya tó sèkìlọ̀ náà níbi ìpàdé oníròyìn nílu Abuja, wá rọ àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàijírìa láti joyè ojú lalákaàn fi sọ́rí ní gbogbo ìgbà.

Ọmọwe Afunanya kò sài rọ àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ asòfin ill yí àti tìpínlẹ̀ tófimọ́ àwọn òsìsẹ́ ìjọba àti taládani tí wọ́n rìnrìn àjò fọ́dún láti máà joyè ojú lalákàn fi sọ́rí.

Ó wá rọ àwọn tón sàtìlẹ́yìn fún ìwà ọ̀daràn nílẹ̀yí láti tọwọ́ ọmọ wọn bọsọ.

Fadahunsi/Ọlaọpa  

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *